Baálẹ̀
Appearance
Baálẹ̀ ni orúko oyè tí Yorùbá n pè olórí abúlé tàbí agbègbè kan. Bakanna Baálẹ̀ (mayor) ni olórí ìjoba ìlú tàbí ìjọba ìbílẹ̀ kan. Àwọn ọmọ-ìlú ni wón máa n jẹ oyè Baálẹ̀. Àwọn báálẹ̀ máa n jẹ́ aṣojú Ọba aládé ní àwọn ìlú kéréjekéréje tí ó bá wà lábé àkóso irú ọba bẹ́ẹ̀. Oba alade ni won maa n fi Baale joye nile Yoruba[1]
A ní ipele mẹ́ta nínu ìjọba ilé Yorùbá. Èyí ni ipò ọba, àwọn ìjòyè gíga rẹ̀ àti àwọn Báálẹ̀.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Olubadan installs four new Mogajis, one Baale - Nigeria and World NewsGuardian Arts - The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News. Retrieved 2019-09-17.
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2016/04/olubadan-council-places-eze-ndigbo-baales/amp/